Mátíù 25:14 BMY

14 “A sì tún fi ìjọba ọ̀run wé ọkùnrin kan tí ó ń lọ sí ìrìn-àjò. Ó pe àwọn ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó sì kó ohun ìní rẹ̀ fún wọn.

Ka pipe ipin Mátíù 25

Wo Mátíù 25:14 ni o tọ