Mátíù 25:19 BMY

19 “Lẹ́yìn ọjọ́ pípẹ́, olúwa àwọn ọmọ-ọ̀dọ̀ dé láti àjò rẹ̀. Ó pè wọ́n jọ láti bá wọn sírò owó rẹ̀.

Ka pipe ipin Mátíù 25

Wo Mátíù 25:19 ni o tọ