Mátíù 25:22 BMY

22 “Èyí tí ó gba tálẹ́ǹtì méjì wí pé ‘Olúwa, ìwọ fún mi ní tálẹ́ǹtì méjì láti lò, èmi sì ti jèrè tálẹ́ńtì méjì mìíràn.’

Ka pipe ipin Mátíù 25

Wo Mátíù 25:22 ni o tọ