Mátíù 25:38 BMY

38 Tàbí tí o jẹ́ àlejò tí a gbà ó sínú ilé wa? Tàbí tí o wà ní ìhòòhò, tí a sì daṣọ bò ọ́?

Ka pipe ipin Mátíù 25

Wo Mátíù 25:38 ni o tọ