Mátíù 26:38 BMY

38 Nígbà náà ni ó wí fún wọn pé, “Ọkàn mi gbọgbẹ́ pẹ̀lú ìbànújẹ́ títí dé ojú ikú, ẹ dúró níhìn-ín yìí, kí ẹ máa ṣọ́nà pẹ̀lú mi.”

Ka pipe ipin Mátíù 26

Wo Mátíù 26:38 ni o tọ