57 Àwọn tí ó mú Jésù fà á lọ sí ilé Káíáfà, olórí àlùfáà, níbi ti àwọn olúkọ́ òfin àti gbogbo àwọn àgbààgbà Júù péjọ sí.
Ka pipe ipin Mátíù 26
Wo Mátíù 26:57 ni o tọ