11 Nígbà náà ni Jésù dúró níwájú Baálẹ̀ láti gba ìdájọ́. Baálẹ̀ sì béèrè pé, “Ṣe ìwọ ni Ọba àwọn Júù?”Jésù dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, nítorí tí ìwọ wí i.”
Ka pipe ipin Mátíù 27
Wo Mátíù 27:11 ni o tọ