Mátíù 27:20 BMY

20 Ṣùgbọ́n àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà Júù rọ àwọn ènìyàn, láti béèrè kí a dá Bárábà sílẹ̀, kí a sì béèrè ikú fún Jésù.

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:20 ni o tọ