Mátíù 27:27 BMY

27 Nígbà náà ni àwọn ọmọ-ogun baálẹ̀ mú Jésù lọ sí gbọ̀ngàn ìdájọ́ wọ́n sì kó gbogbo ẹgbẹ́ ọmọ-ogun tì í

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:27 ni o tọ