Mátíù 27:32 BMY

32 Bí wọ́n sì ti ń jáde, wọ́n rí ọkùnrin kan ará Kíréné tí à ń pè ní Símónì. Wọ́n sì mú ọkùnn náà ní túlààsì láti ru àgbélébùú Jésù.

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:32 ni o tọ