60 Ó sì tẹ́ ẹ sínú ibojì òkúta tí ó gbẹ́ nínú àpáta fúnraa rẹ̀. Ó sì yí òkúta ńlá dí ẹnu ọ̀nà ibojì náà, ó sì lọ.
Ka pipe ipin Mátíù 27
Wo Mátíù 27:60 ni o tọ