Mátíù 27:66 BMY

66 Nítorí náà wọ́n lọ. Wọ́n sì ṣé òkúta ibojì náà dáadáa. Wọ́n sì fi àwọn olùṣọ́ sí ibẹ̀ láti dáàbò bò ó.

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:66 ni o tọ