Mátíù 28:14 BMY

14 Bí Baálẹ̀ bá sì mọ̀ nípa rẹ̀, àwa yóò ṣe àlàyé tí yóò tẹ́ ẹ lọ́rùn fún un, tí ọ̀rọ̀ náà kì yóò fi lè kó bá yín.”

Ka pipe ipin Mátíù 28

Wo Mátíù 28:14 ni o tọ