Mátíù 3:14 BMY

14 Ṣùgbọ́n Jòhánù kò fẹ́ ṣe ìtẹ̀bọmi fún un, ó wí pé, “Ìwọ ni ì bá ṣe ìbamitíìsì fún mi, ṣé ìwọ tọ̀ mí wá fún ìbamitíìsì?”

Ka pipe ipin Mátíù 3

Wo Mátíù 3:14 ni o tọ