5 Àwọn ènìyàn jáde lọ sọ́dọ̀ rẹ̀ láti Jerúsálémù àti gbogbo Jùdíà àti àwọn ènìyàn láti gbogbo ìhà Jọ́dánì.
Ka pipe ipin Mátíù 3
Wo Mátíù 3:5 ni o tọ