Mátíù 3:9 BMY

9 Kí ẹ má sì ṣe rò nínú ara yin pé, ‘Àwa ní Ábúráhámù ní baba.’ Èmi wí fún yín, Ọlọ́run lè mu àwọn ọmọ jáde láti inú àwọn òkúta wọ̀nyí wá fún Ábúráhámù.

Ka pipe ipin Mátíù 3

Wo Mátíù 3:9 ni o tọ