Mátíù 5:1 BMY

1 Nígbà tí ó rí ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó gun orí òkè lọ ó sì jókòó. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ si tọ̀ ọ́ wá.

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:1 ni o tọ