Mátíù 5:11 BMY

11 “Alábùkún-fún ni ẹ̀yin nígbà tí àwọn ènìyàn bá fi àbùkù kàn yín tí wọn bá ṣe inúnibíni sí yín, ti wọn fi ètè èké sọ̀rọ̀ búburú gbogbo sí yín nítorí mi.

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:11 ni o tọ