Mátíù 5:17 BMY

17 “Ẹ má se rò pé, èmí wá láti pa òfin àwọn wòlíì run, èmi kò wá láti pa wọn rẹ́, bí kò ṣe láti mú wọn ṣẹ.

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:17 ni o tọ