26 Lóòótọ ni mo wí fún ọ, ìwọ kì yóò jáde kúrò níbẹ̀ títítí ìwọ yóò fi san ẹyọ owó kan tí ó kù.
Ka pipe ipin Mátíù 5
Wo Mátíù 5:26 ni o tọ