Mátíù 5:34 BMY

34 Ṣùgbọ́n èmi wí fún yín, Ẹ má ṣe búra rárá,: ìbáà ṣe ìfi-ọ̀run-búra, nítorí ìtẹ́ Ọlọ́run ni.

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:34 ni o tọ