Mátíù 5:39 BMY

39 Ṣùgbọ́n èmi wí fún yín pé, ‘Ẹ má ṣe tako ẹni ibi. Bí ẹnì kan bá gbá ọ lẹ́rẹ̀kẹ́ ọ̀tún, yí ẹ̀rẹ̀kẹ́ òsì sí olúwa rẹ̀ pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:39 ni o tọ