Mátíù 7:14 BMY

14 Nítorí kékeré ni ẹnu-ọ̀nà náà, tóóró sì ni ojú ọ̀nà náà, ti ó lọ sí ibi ìyè, díẹ̀ ni àwọn ẹni tí ó ń rìn ín.

Ka pipe ipin Mátíù 7

Wo Mátíù 7:14 ni o tọ