Mátíù 8:18 BMY

18 Nígbà tí Jésù rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó yí i ká, ó pàṣẹ pé kí wọ́n sọdá sí òdìkejì adágún.

Ka pipe ipin Mátíù 8

Wo Mátíù 8:18 ni o tọ