Mátíù 9:33 BMY

33 Nígbà tí a lé ẹ̀mí èṣù náà jáde, ọkùnrin tí ó ya odi sì fọhùn. Ẹnu sì ya àwọn ènìyàn, wọ́n wí pé, “A kò rí irú èyí rí ní Ísírẹ́lì.”

Ka pipe ipin Mátíù 9

Wo Mátíù 9:33 ni o tọ