24 Ẹni tí ń fi tọkàntọkàn ṣiṣẹ́ ni yóo máa jẹ́ olórí,ṣugbọn ọ̀lẹ ni a óo máa mú ṣiṣẹ́ tipátipá.
Ka pipe ipin Ìwé Òwe 12
Wo Ìwé Òwe 12:24 ni o tọ