25 Ọ̀pọ̀ ìpayà máa ń kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá eniyan,ṣugbọn ọ̀rọ̀ rere a máa mú inú eniyan dùn.
Ka pipe ipin Ìwé Òwe 12
Wo Ìwé Òwe 12:25 ni o tọ