Ìwé Òwe 6:22 BM

22 Nígbà tí o bá ń lọ, wọn yóo máa tọ́ ọ,bí o bá sùn, wọn yóo máa ṣọ́ ọ,bí o bá jí, wọn yóo máa bá ọ sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 6

Wo Ìwé Òwe 6:22 ni o tọ