Ìwé Òwe 8:8 BM

8 Òdodo ni gbogbo ọ̀rọ̀ ẹnu mi,kò sí ìtànjẹ tabi ọ̀rọ̀ àrékérekè ninu wọn.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 8

Wo Ìwé Òwe 8:8 ni o tọ