Ìwé Òwe 8:9 BM

9 Gbogbo ọ̀rọ̀ náà tọ́ lójú ẹni tí ó mòye,wọn kò sì ní àbùkù lọ́dọ̀ àwọn tí wọ́n ní ìmọ̀.

Ka pipe ipin Ìwé Òwe 8

Wo Ìwé Òwe 8:9 ni o tọ