Kronika Keji 1:10 BM

10 Fún mi ní ọgbọ́n ati ìmọ̀ tí n óo fi máa ṣe àkóso àwọn eniyan wọnyi, nítorí pé ó ṣòro fún ẹnikẹ́ni láti ṣe àkóso àwọn eniyan rẹ tí wọ́n pọ̀ tó báyìí.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 1

Wo Kronika Keji 1:10 ni o tọ