Kronika Keji 1:9 BM

9 OLUWA, Ọlọrun, mú ìlérí tí o ṣe fún Dafidi, baba mi, ṣẹ nisinsinyii, nítorí pé o ti fi mí jọba lórí àwọn eniyan tí wọ́n pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 1

Wo Kronika Keji 1:9 ni o tọ