Kronika Keji 1:8 BM

8 Solomoni dá Ọlọrun lóhùn, ó ní “O ti fi ìfẹ́ ńlá tí kìí yẹ̀ han Dafidi, baba mi, o sì ti fi mí jọba nípò rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 1

Wo Kronika Keji 1:8 ni o tọ