Kronika Keji 1:7 BM

7 Ní òru ọjọ́ náà, Ọlọrun fara han Solomoni, ó wí fún un pé “Bèèrè ohun tí o bá fẹ́ kí n fún ọ.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 1

Wo Kronika Keji 1:7 ni o tọ