11 Àwọn wolii yòókù ń sọ bákan náà, wọ́n ń wí pé, “Lọ gbógun ti Ramoti Gileadi, o óo ṣẹgun. OLUWA yóo fi wọ́n lé ọba lọ́wọ́.”
Ka pipe ipin Kronika Keji 18
Wo Kronika Keji 18:11 ni o tọ