Kronika Keji 18:12 BM

12 Iranṣẹ tí ó lọ pe Mikaya sọ fún un pé, “Àsọtẹ́lẹ̀ kan náà ni gbogbo àwọn wolii ń sọ, pé ọba yóo ṣẹgun, ìwọ náà sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 18

Wo Kronika Keji 18:12 ni o tọ