Kronika Keji 18:20 BM

20 Nígbà náà ni ẹ̀mí kan jáde, ó sì dúró níwájú OLUWA, ó ní, ‘N óo lọ tan Ahabu jẹ.’ OLUWA bá bèèrè pé, ‘Ọgbọ́n wo ni o fẹ́ dá?’

Ka pipe ipin Kronika Keji 18

Wo Kronika Keji 18:20 ni o tọ