Kronika Keji 20:23 BM

23 Àwọn ọmọ ogun Amoni, ati Moabu gbógun ti àwọn ará Òkè Seiri wọ́n sì pa wọ́n run patapata. Lẹ́yìn náà, wọ́n dojú ìjà kọ ara wọn, wọ́n sì pa ara wọn run.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:23 ni o tọ