Kronika Keji 20:24 BM

24 Nígbà tí ogun Juda dé ilé ìṣọ́ tí ó wà ninu aṣálẹ̀, wọ́n wo àwọn ọ̀tá wọn, wọ́n sì rí i pé wọ́n ti kú sílẹ̀ lọ bẹẹrẹ; kò sí ẹni tí ó sá àsálà ninu wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:24 ni o tọ