Kronika Keji 20:26 BM

26 Ní ọjọ́ kẹrin, wọ́n péjọ ní àfonífojì Beraka. Ibẹ̀ ni wọ́n ti yin OLUWA. Nítorí náà ni wọ́n ṣe bẹ̀rẹ̀ sí pe ibẹ̀ ní Beraka títí di òní olónìí.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:26 ni o tọ