Kronika Keji 20:27 BM

27 Jehoṣafati kó gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ pada sí Jerusalẹmu pẹlu ayọ̀ ìṣẹ́gun, nítorí pé OLUWA ti fún un ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 20

Wo Kronika Keji 20:27 ni o tọ