Kronika Keji 26:8 BM

8 Àwọn ará Amoni ń san ìṣákọ́lẹ̀ fún Usaya, òkìkí rẹ̀ kàn káàkiri títí dé agbègbè ilẹ̀ Ijipti, nítorí pé ó di alágbára gan-an.

Ka pipe ipin Kronika Keji 26

Wo Kronika Keji 26:8 ni o tọ