Kronika Keji 26:9 BM

9 Usaya tún kọ́ àwọn ilé ìṣọ́ ní Jerusalẹmu níbi Ẹnubodè tí ó wà ní igun odi, ati sí ibi Ẹnubodè àfonífojì, ati níbi Ìṣẹ́po Odi. Ó sì mọ odi sí wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 26

Wo Kronika Keji 26:9 ni o tọ