Kronika Keji 28:19 BM

19 OLUWA rẹ Juda sílẹ̀ nítorí Ahasi, ọba Juda, nítorí pé ó hùwà ìríra ní Juda, ó sì ṣe aiṣootọ sí OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 28

Wo Kronika Keji 28:19 ni o tọ