Kronika Keji 28:20 BM

20 Nítorí náà Tigilati Pileseri, ọba Asiria gbógun ti Ahasi, ó sì fìyà jẹ ẹ́, dípò kí ó ràn án lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Kronika Keji 28

Wo Kronika Keji 28:20 ni o tọ