Kronika Keji 29:32 BM

32 Àwọn nǹkan tí wọn mú wá jẹ́ aadọrin akọ mààlúù, ọgọrun-un (100) àgbò, igba (200) ọ̀dọ́ aguntan, gbogbo rẹ̀ wà fún ẹbọ sísun sí OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 29

Wo Kronika Keji 29:32 ni o tọ