Kronika Keji 29:33 BM

33 Àwọn ẹran tí wọ́n yà sọ́tọ̀ fún ẹbọ jẹ́ ẹgbẹta (600) akọ mààlúù, ati ẹgbẹẹdogun (3,000) aguntan.

Ka pipe ipin Kronika Keji 29

Wo Kronika Keji 29:33 ni o tọ