Kronika Keji 33:2 BM

2 Ó ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA. Gbogbo nǹkan ẹ̀gbin tí àwọn orílẹ̀-èdè tí OLUWA lé jáde fún àwọn ọmọ Israẹli máa ń ṣe ni òun náà ṣe.

Ka pipe ipin Kronika Keji 33

Wo Kronika Keji 33:2 ni o tọ