Kronika Keji 33:3 BM

3 Gbogbo ibi ìrúbọ tí Hesekaya, baba rẹ̀ ti wó lulẹ̀ ni ó tún kọ́. Ó tẹ́ pẹpẹ fún Baali, ó sì ri àwọn òpó fún Aṣera. Ó ń bọ àwọn ìràwọ̀, ó sì ń sìn wọ́n.

Ka pipe ipin Kronika Keji 33

Wo Kronika Keji 33:3 ni o tọ