Kronika Keji 34:6 BM

6 Bákan náà ni ó ṣe ní àwọn ìlú Manase, ati ti Efuraimu, ati àwọn ìlú ilẹ̀ Simeoni títí dé ilẹ̀ Nafutali, ati ní gbogbo àyíká wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:6 ni o tọ